Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù sì wí fún wọn pé, “Ẹ ronúpìwàdà, kí a sì bamitíìsì olúkúkùkù yín ní orúkọ Jésù Kírísítì fún ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ yín. Ẹ̀yin yóò sì gba ẹbun Ẹ̀mí Mímọ́

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:37-46