Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì gbọ́, ọkàn wọn gbọgbẹ́, wọn sì wí fún Pétérù àti àwọn àpósítélì yòókù pé, “Ará, kín ni àwa yóò ṣe”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:36-42