Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ǹjẹ́ kí gbogbo ilé Ísírẹ́lì mọ̀ dájúdájú pé: Ọlọ́run ti fi Jésù náà, ti ẹ̀yin kàn mọ́ àgbélébùú, se Olúwa àti Kírísítì.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:27-39