Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì tí wí nípa tirẹ̀ pé:“ ‘Mo rí Olúwa nígbà gbogbo niwájú mí,nítorí tí ó ń bẹ lọ́wọ́ ọ̀tún mi,A kì ó ṣí mi ní ipò.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 2:18-34