Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì sọ fún Pọ́ọ̀lù lóru ni ojúran pé, “Má bẹ̀rù, sá máa sọ, má sì se pá ẹnu rẹ̀ mọ́:

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:4-19