Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kírísípù, olórí ṣínágọ́gù, sì gba Olúwa gbọ́ pẹ̀lú gbogbo ilé rẹ̀: àti ọ̀pọ̀ nínú àwọn ara Kọ́ríńtì, nígbà tí wọ́n gbọ́, wọ́n gbàgbọ́, a sì bamitíìsì wọn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:6-15