Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí èmí wà pẹ̀lú rẹ, kò sì sí ẹni tí yóò dìde sí ọ láti pa ọ lára: nítorí mo ní ènìyàn púpọ̀ ni ìlú yìí.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 18:3-20