Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí gbogbo àwọn ará Áténì, àti àwọn àlejò tí ń ṣe àtìpó níbẹ̀ kì í ṣe ohun mìíràn jù kí a máa sọ tàbí ki a máa gbọ́ ohun titun lọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:18-31