Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí ìwọ mú ohun àjèjì wá si etí wa: àwa sì ń fẹ́ mọ̀ kín ni ìtumọ̀ nǹkan wọ̀nyí.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:18-27