Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pọ́ọ̀lù si dìde dúró láàrin Áréópágù, ó ní, “Ẹ̀yin ará Áténì, mo wòye pé ní ohun gbogbo ẹ kún fún onírúurú ìsìn jù.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 17:12-32