Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn dúró ti i yíká, ó dìde ó sì padà wọ inú ìlú náà lọ. Ní ọjọ́ kejì ó bá Bánábà lọ sí Dábè.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:14-28