Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn Júù kan sì ti Áńtíókù àti Ìkóníónì wá, nígbà tí wọ́n yí àwọn ènìyàn lọ́kan padà, wọ́n sì sọ Pọ́ọ̀lù ní òkúta, wọ́n wọ́ ọ kúrò sí ẹ̀yin odi ìlú náà, wọn ṣèbí ó kú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:18-26