Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n sì ti wàásù ìyìn rere fún ìlú náà, tí wọ́n sì ni ọmọ-ẹ̀yìn púpọ̀, wọn padà lọ sí Lísírà, àti Ikóníónì, àti Áńtíókù,

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:12-25