Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Díẹ̀ ni ó kù kí wọn má le fi ọ̀rọ̀ wọ̀nyí dá àwọn ènìyàn dúró, kí wọn má ṣe rúbọ bọ wọ́n.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:14-21