Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ó sì wí nínú Sáàmù mìíràn pẹ̀lú pé:“ ‘Ìwọ kí yóò jẹ́ kí Ẹni Mímọ́ rẹ rí ìdíbàjẹ́.’

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:26-41