Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí lẹ́yìn ìgbà ti Dáfídì ti sin ìran rẹ tan nípa Ìfẹ́ Ọlọ́run, ó sùn, a sì tẹ́ ẹ ti àwọn baba rẹ̀, ara rẹ̀ sì rí ìdíbàjẹ́.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:30-44