Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ni tí pé Ọlọ́run jí i dìde kúrò nínú òkú, ẹni tí kì yóò tún padà sí ìbàjẹ́ mọ́, ó wí báyí pé:“ ‘Èmi ó fún yín ní ọ̀rẹ́ mímọ́ Dáfídì, tí ó dájú.’

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:33-38