Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n mo dáhùn wí pé, ‘Àgbẹdọ̀, Olúwa! nítorí ohun èèwọ̀ tàbí ohun aláìmọ́ kan kò wọ ẹnu mi rí láí.’

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:7-15