Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì gbọ́ ohùn kan ti ó fọ̀ sí mi pé, ‘Dìde, Pétérù: máa pa, kí ó sì máa jẹ.’

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:1-17