Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣùgbọ́n ohùn kan dáhùn nígbà ẹ̀ẹ̀kéjì láti ọ̀run wá pé, ‘Ohun tí Ọlọ́run bá ti wẹ̀mọ́, kí ìwọ má ṣe pè é ní àìmọ́.’

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:4-15