Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo tẹjúmọ́ ọn, mo sì fiyèsí i, mo sí rí ẹran ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin, àti ẹranko ìgbẹ́, àti ohun tí ń rákò, àti ẹyẹ ojú ọ̀run.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:4-11