Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi wà ni ìlú Jópà, mo ń gbàdúrà, mo rí ìran kan lójúran. Ohun èlò kan sọ̀kalẹ̀ bí ewé tákàdá ńlá, tí a ti igun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ láti ọ̀run wá; ó sì wá títí de ọ̀dọ̀ mi.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:1-9