Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Pétérù sì ti ń sọ ọ̀rọ̀ wọ̀nyí lẹ́nu, Ẹ̀mí Mímọ́ bà lé gbogbo àwọn ti ó gbọ́ ọ̀rọ̀ náà.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:42-48