Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnu sì yà àwọn onígbàgbọ́ ti ìkọlà tí wọ́n bá Pétérù wá, nítorí ti a tu ẹ̀bùn Ẹ̀mí Mímọ́ sórí àwọn aláìkọlà pẹ̀lú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:38-48