Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun ni gbogbo àwọn wòlíì jẹ́rìí sì pé, ẹnikẹ́ni ti ó bá gbà á gbọ́ yóò rí ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ gbà nípa orúkọ rẹ̀.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:33-48