Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì paṣẹ fún wa láti wàásù fún àwọn ènìyàn, àti láti jẹ́rìí pé, òun ni a ti ọwọ́ Ọlọ́run yàn ṣe Onídàjọ́ ààyè àti òkú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:32-46