Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run rán sí àwọn ọmọ Isírẹ́lì, nígbà tí a wàásù àlàáfíà nípa Jésù Kírísítì (Òun ni Olúwa ohun gbogbo)

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:32-43