Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ni gbogbo orílẹ̀-èdè, ẹni tí ó bá bẹ̀rù rẹ̀, ti ó sì ń ṣisẹ́ òdodo, ẹni ìtẹ́wọ́gbà ni lọ́dọ̀ rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:27-38