Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin náà mọ ọ̀rọ̀ náà tí a kéde rẹ̀ yíká gbogbo Jùdíà, tí a bẹ̀rẹ̀ rẹ̀ láti Gálílì, lẹ́yìn bamitíìsímù ti Jòhánù wàásù rẹ̀.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:28-47