Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pétérù sì ya ẹnu rẹ, ó sì wí pé, “Nítòótọ́ mo wòye pé, Ọlọ́run kì í ṣe ojusajú ènìyàn.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:28-37