Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Pétérù gbé e dìde, ó ni, “Dìde; ènìyàn ni èmi tìkárami pẹ̀lú.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:18-36