Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó sì ti ń bá a sọ̀rọ̀, ó wọlé, ó sì rí àwọn ènìyàn púpọ̀ tí wọ́n péjọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:19-36