Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe bí Pétérù ti ń wọlé, Kọ̀nélíù pàdé rẹ̀, ó wólẹ̀ lẹ́ṣẹ̀ rẹ̀, ó sì foríbalẹ̀ fún un.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:23-28