Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ́jọ́ kejì wọ́n sì wọ Kesaríà, Kọ̀nélíù sì ti ń rétí wọn, ó sì ti pe àwọn ìbátan àti àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ tímọ́tímọ́ jọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:19-30