Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni ó pè wọ́n wọlé, ó gbà wọ́n lálejò.Níjọ́ kejì, ó sì dìde, ó bá wọn lọ, nínú àwọn arákùnrin ní Jopa sì bá a lọ pẹ̀lú.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:20-29