Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Njẹ́ dìde, sọ̀kalẹ̀ kí ó sì bá wọn lọ, má ṣe kọminú ohunkohun: nítorí èmi ni ó rán wọn.”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:15-27