Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Pétérù sì ti ń ronú ìran náà, Ẹ̀mí wí fún un pé, “Wò ó, àwọn ọkùnrin mẹ́ta ń wá ọ.

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:14-21