Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Pétérù sọ̀kalẹ̀ tọ àwọn ọkùnrin náà tí a rán, ó sì wí pé, “Wò ó, èmi ni ẹni tí ẹ̀yin ń wá: kín ni ìdí tẹ̀ ti ẹ fi wá?”

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 10:17-22