Hágáì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Èyí ni ohun tí Èmi fi bá a yín dá májẹ̀mú nígbà tí ẹ jáde kúrò ní Éjíbítì, bẹ́ẹ̀ ni Ẹ̀mí ì mi sì wà pẹ̀lú yín. Ẹ má ṣe bẹ̀rù.’

Hágáì 2

Hágáì 2:1-7