Hágáì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: ‘Láìpẹ́ jọjọ, Èmi yóò mi àwọn ọrun àti ayé, òkun àti ìyàngbẹ ilẹ̀ lẹ́ẹ̀kan sí i.

Hágáì 2

Hágáì 2:3-15