Hágáì 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n nísinsin yìí, múra gírí, ìwọ Sérúbábélì,’ ni Olúwa wí. ‘Múra gírí, ìwọ Jóṣúà ọmọ Jósédékì, olórí àlùfáà. Ẹ sì múra gírí gbogbo ẹ̀yin ènìyàn ilẹ̀ náà;’ ni Olúwa wí, ‘kí ẹ sì ṣiṣẹ́. Nítorí èmi wà pẹ̀lú yín;’ ni Olúwa àwọn ọmọ ogun wí.

Hágáì 2

Hágáì 2:1-7