Ẹkún Jeremáyà 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni àmì òróró Olúwa, èémí ìyè wa,ni wọ́n fi tàkúté wọn mú.Àwa rò pé lábẹ́ òjìji rẹ̀ni àwa yóò máa gbé láàrin orílẹ̀-èdè gbogbo.

Ẹkún Jeremáyà 4

Ẹkún Jeremáyà 4:10-22