Ẹkún Jeremáyà 4:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ń lé wa yáraju idì ojú ọ̀run lọ;wọ́n lé wa ní gbogbo orí òkèwọ́n sì gẹ̀gùn dè wá ní ihà.

Ẹkún Jeremáyà 4

Ẹkún Jeremáyà 4:10-22