Ẹkún Jeremáyà 4:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ yọ̀ kí inú yín sì dùn, ẹ̀yin ọmọbìnrin Édómù,ẹ̀yin tó ń gbé ní ilẹ̀ Húsì.Ṣùgbọ́n, a ó gbé aago náà kọjá sọ́dọ̀ rẹ pẹ̀lú;ìwọ yóò yó bí ọ̀mùtí, ìwọ yóò sì rìn ní ìhòòhò.

Ẹkún Jeremáyà 4

Ẹkún Jeremáyà 4:17-22