Ẹkún Jeremáyà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀gànjọ́ òru ni ó fi máa ń sunkún kíkoròpẹ̀lú omijé tí ó dúró sí ẹ̀rẹ̀kẹ́ rẹ̀.Nínú gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ̀kò sí ọ̀kan nínú wọn láti rẹ̀ ẹ́ lẹ́kún.Gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ti jọ̀wọ́ rẹ̀wọ́n ti di alátakò rẹ̀.

Ẹkún Jeremáyà 1

Ẹkún Jeremáyà 1:1-3