Ẹkún Jeremáyà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ìjìyà àti ìpọ́njú nínú oko ẹrú,Júdà lọ sí àjòÓ tẹ̀dó láàrin àwọn orílẹ̀ èdè,ṣùgbọ́n kò rí ibi ìsinmi.Àwọn tí ó ń tẹ̀le ká a mọ́ibi tí kò ti le sá àṣálà.

Ẹkún Jeremáyà 1

Ẹkún Jeremáyà 1:1-6