Ékísódù 36:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọ́n sì ṣe òpó márùn-ún pẹ̀lú ìkọ́ wọn. Wọ́n bo orí àwọn òpó náà àti ìgbànú wọn pẹ̀lú wúrà, wọn sì ṣe ihò ìtẹ̀bọ̀ márùn-ún wọn ní idẹ.

Ékísódù 36

Ékísódù 36:32-38