Ékísódù 36:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ẹnu ọ̀nà Àgọ́ náà wọ́n ṣe aṣọ títa ti aṣọ aláró, ti elésèé àlùkù, ti òdòdò àti ti ọ̀gbọ̀ olókùn dáradára iṣẹ́ abẹ́rẹ́;

Ékísódù 36

Ékísódù 36:28-38