Ékísódù 37:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bésálélì se àpótí igi kasíá ìgbọ̀nwọ́ méjì ààbọ̀ ni gígùn rẹ̀, ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀ ni fífẹ̀ rẹ̀, ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀ ni gíga rẹ̀.

Ékísódù 37

Ékísódù 37:1-3