Ékísódù 26:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo aṣọ títa náà ni kí ó jẹ́ déédé ìgbọ̀nwọ́ mèjídínlọ́gbọ̀n ní gígùn àti ìgbọ̀nwọ́ mẹ́rin ni fífẹ̀.

Ékísódù 26

Ékísódù 26:1-5